Róòmù 6:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọpẹ́ ni fún Ọlọ́run pé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀yin ti se ìgbọ́ràn, pẹ̀lú ọkàn yín, sí ẹ̀kọ́ èyí tí Ọlọ́run fi lé yín lọ́wọ́.

Róòmù 6

Róòmù 6:12-23