Róòmù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mélòó mélòó sì ni tí a dá wa láre nísinn yìí nípa ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ni a ó gbà wá là kúrò nínú ìbínú nípaṣẹ̀ rẹ̀.

Róòmù 5

Róòmù 5:6-15