Róòmù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni a ṣe kà á sí i? Nígbà tí ó wà ní ìkọlà tàbí ní àìkọlà? Kì í ṣe ni ìkọlà, ṣùgbọ́n ní àìkọlà ni.

Róòmù 4

Róòmù 4:9-13