Róòmù 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wí pé, a rán Kírísítì láti ṣe ìránṣẹ́ àwọn tí se Júù nítorí òtítọ́ Ọlọ́run, láti fi ìdí àwọn ìlérí tí a ti ṣe fún àwọn baba múlẹ̀,

Róòmù 15

Róòmù 15:1-9