Róòmù 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ẹ̀yin kí ó lè fi ọkàn kan àti ẹnu kan fi ògo fún Ọlọ́run, Baba Olúwa wa Jésù Kírísítì.

Róòmù 15

Róòmù 15:1-7