Róòmù 15:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a lè kó mi yọ kúrò lọ́wọ́ àwọn aláìgbàgbọ́ ní Jùdíà àti kí isẹ́ ìránsẹ́ tí mo ní sí Jérúsálẹ́mù le jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn mímọ́ níbẹ̀.

Róòmù 15

Róòmù 15:27-32