Róòmù 15:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé àwọn tí ó wà ní agbégbé Makedóníà àti agbégbé Ákáyà ti kó ẹ̀bùn jọ fún àwọn talákà tí ó wà ní àárín àwọn ènìyàn mímọ́ ní Jérúsálẹ́mù.

Róòmù 15

Róòmù 15:22-27