Róòmù 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nípa agbára isẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tí a se lọ́wọ́ Ẹ̀mi. Mo ti polongo ìyìn rere Kírísítì ní ẹ̀kún rẹ́rẹ́ láti Jérúsálẹ́mù dé ìlú tí a ń pè ní Ílíríkónì.

Róòmù 15

Róòmù 15:15-20