Róòmù 15:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àìṣáyà sì tún wí pé,“Gbòngbò Jésè kan ń bọ̀ wá,òun ni ẹni tí yóò dìde ṣe àkóso àwọn aláìkọlà;Àwọn aláìkọlà yóò ní ìrètí nínú rẹ̀.”

Róòmù 15

Róòmù 15:4-21