Róòmù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa tí a jẹ́ alágbára nínú ìgbàgbọ́ yẹ kí ó máa ru ẹrù àìlera àwọn aláìlera, kí a má si ṣe ohun tí ó wu ara wa.

Róòmù 15

Róòmù 15:1-7