Róòmù 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí ẹni tí ó bá sin Kírísítì nínú nǹkan wọ̀nyí ni ó se ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ Ọlọ́run, tí ó sì ní ìyìn lọ́dọ̀ ènìyàn.

Róòmù 14

Róòmù 14:8-22