Róòmù 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí inú arakùnrin rẹ ba bàjẹ́ nítorí ohun tí ìwọ́ jẹ, ìwọ kò rìn nínú ìfẹ́ mọ́. Má se fi oúnjẹ rẹ sọ ẹni tí Kírísítì kú fún di ẹni ègbé.

Róòmù 14

Róòmù 14:12-17