Róòmù 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òru bù kọjá tan, ilẹ̀ sì fẹ́rẹ mọ́: nítorí náà ẹ jẹ́ kí a bọ́ ara iṣẹ́ òkùnkùn sílẹ̀, kí a sì gbé ìhámọ́ra ìmọ́lẹ̀ wọ̀.

Róòmù 13

Róòmù 13:11-14