Róòmù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má wà ní inú kan náà sí ara yín. Ẹ má ṣe ronú ohun gíga, ṣùgbọ́n ẹ má tẹ̀lé onírẹ̀lẹ̀. Ẹ má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n ní ojú ara yín.

Róòmù 12

Róòmù 12:7-19