Róòmù 10:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ̀yin ará, ìfẹ́ ọkàn àti àdúrà mi ni pé, kí àwọn Júù rí ìgbàlà.

2. Mo mọ irú ìfẹ́ àti ìtara tí wọ́n ní sí ọlá àti ògo Ọlọ́run, ṣùgbọ́n ọ̀nà ìsìnà ni wọn ń gbà wá Ọlọ́run;

Róòmù 10