Róòmù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọdọ ẹni tí àwa rí oore-ọ̀fẹ́ àti jíjẹ́ Àpósítélì gbà, láti wàásù fún gbogbo ènìyàn orílẹ̀-èdè kí wọn kí ó lè wá sínú ìgbàgbọ́ èyíni ní orúkọ rẹ̀.

Róòmù 1

Róòmù 1:3-12