Òwe 9:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọgbọ́n ti kọ́ ilé rẹ̀,ó ti gbẹ́ òpó o rẹ̀ méjèèjì

2. ó ti fi ilé pọn tí ó ti fọ̀nà rokàó sì ti ṣètò o tábìlì oúnjẹ rẹ̀

3. ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde, ó sì ń pè,láti ibi tí ó ga jù láàrin ìlú.

Òwe 9