Òwe 7:25-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

25. Má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yà sí ọ̀nà rẹ̀,tàbí kí ó rìn lọ sí ipa ọ̀nà rẹ̀.

26. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí ó ti fà lulẹ̀Ogunlọ́gọ̀ àwọn alágbára ni ó ti pa.

27. Ilé e rẹ̀ ni ọ̀nà tààra sí iṣà òkú,tí ó lọ tààra sí àgbàlá ikú.

Òwe 7