Òwe 7:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọmọ mi, pa ọ̀rọ̀ mi mọ́,sì fi àwọn òfin mi pamọ́ sínú ọkàn rẹ.

2. Pa òfin mi mọ́, ìwọ yóò sì yètọ́jú ẹ̀kọ́ mi bí ẹyinlójú rẹ

3. Kọ wọ́n sí ọwọ́ òsì rẹ, má ṣe fi jẹunkọ wọ́n sí inú ọkàn rẹ.

Òwe 7