Òwe 5:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọmọ mi, fiyè sí ọgbọ́n ọ̀n mi tẹ́tí sílẹ̀ dáradára sí ọ̀rọ̀ àròjinlẹ̀mi

2. kí ìwọ sì lè ní ìṣọ́rakí ètè rẹ sì le pa ìmọ̀ mọ́.

Òwe 5