Òwe 31:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dìde nígbà tí òkùnkùn sì kùn;ó ṣe oúnjẹ fún ìdílé rẹ̀àti ìpín oúnjẹ fún àwọn ìránṣẹ́-bìnrin rẹ̀.

Òwe 31

Òwe 31:13-25