Òwe 30:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àìṣe bẹ́ẹ̀, mo lè ní àníjù kí n sì gbàgbé rẹkí ń sì wí pé, ‘Ta ni Olúwa?’Tàbí kí ń di òtòsì kí ń sì jalèkí ń sì ṣe àìbọ̀wọ̀ fún orúkọ Ọlọ́run mi.

Òwe 30

Òwe 30:1-18