Òwe 3:23-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Nígbà náà ni ìwọ yóò bá ọ̀nà rẹ lọ ní àìṣéwu,ìwọ kì yóò sì kọsẹ̀;

24. Nígbà tí ìwọ bá dùbúlẹ̀, ìwọ kì yóò bẹ̀rùnígbà tí ìwọ bá dùbúlẹ̀, oorun rẹ yóò jẹ́ oorun ayọ̀

25. má ṣe bẹ̀rù ìdàámú òjijìtàbí ti ìparun tí ó ń dé bá àwọn ènìyàn búburú

Òwe 3