Òwe 29:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìdájọ́ òdodo ni ọba fi í mú ìlú tòrò nini,ṣùgbọ́n èyí tí ń ṣojúkòkòrò àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fà á lulẹ̀.

Òwe 29

Òwe 29:1-5