Ẹni tí ó ń fifún talákà kì yóò ṣe aláìní ohunkóhunṣùgbọ́n ẹni tí ó di ojú rẹ̀ sí wọn gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ègún.