Òwe 28:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó bá ro ilẹ̀ rẹ̀ yóò ní oúnjẹ lọ́pọ̀lọpọ̀ṣùgbọ́n ẹni tí ń lé ohun aṣán yóò kún fún òsì.

Òwe 28

Òwe 28:13-24