Òwe 28:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ó bẹ̀rù Olúwa nígbà gbogboṣùgbọ́n ẹni tí ó ṣé ọkàn rẹ̀ le bọ́ sínú wàhálà.

Òwe 28

Òwe 28:10-15