Nígbà tí olódodo ń lékè ariwo ayọ̀ ta;ṣùgbọ́n nígbà tí ènìyàn búburú gorí òye, àwọn ènìyàn a na pápá bora.