Òwe 27:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí omi tí ń ṣe àfihàn ojú, nígbà tí a bá wò óbẹ́ẹ̀ ni ọkàn ènìyàn ń ṣe àfihàn ènìyàn.

Òwe 27

Òwe 27:9-22