Òwe 27:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gba aṣọ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àjòjìfi ṣe ẹ̀rí ìdúró bí o bá ṣe onídùúró fún obìnrin oní ìṣekúṣe.

Òwe 27

Òwe 27:5-23