Òwe 26:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Bí òjò dídì tàbí òjò ní ìgbà ìkórèọlá kò yẹ aláìgbọ́n ènìyàn.

2. Bí ológoṣẹ́ tí ń sí kiri tàbí alápáǹdẹ̀dẹ̀ tí ń rá bàbàÈpè kò le è mọ́ ẹni tí kò ṣiṣẹ́ èpèÈpè kì í jani bí a kò bá ṣiṣẹ́ èpè.

3. Lagbà fún ẹṣin, ìjánu fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́àti pàṣán fún ẹ̀yìn aṣiwèrè.

Òwe 26