Òwe 25:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ;bí òrùngbẹ bá ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mú.

Òwe 25

Òwe 25:14-25