Òwe 25:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ojú ṣíṣú àti afẹ́fẹ́ láì sí òjòni ènìyàn tí ń yangàn nípa ẹ̀bùn tí kò fún ni.

Òwe 25

Òwe 25:11-22