Òwe 23:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Baba olódodo ni yóò yọ̀ gidigidi:ẹni tí ó sì bí ọmọ ọlọ́gbọ́n,yóò ní ayọ̀ nínú rẹ̀.

Òwe 23

Òwe 23:20-27