Òwe 23:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́, ìwọ ọmọ mi, kí o sì gbọ́n,kí o sì máa tọ́ àyà rẹ sí ọ̀nà títọ́.

Òwe 23

Òwe 23:10-25