Òwe 22:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe bá oníbìínu ènìyàn ṣe ọ̀rẹ́;má sì ṣe bá ọkùnrin onínú-fùfù rìn.

Òwe 22

Òwe 22:18-25