Òwe 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tó ń ni talákà lára láti ní ọrọ̀,tí ó sì ń ta ọlọ́rọ̀ lọ́rẹ,yóò di aláìní bí ó ti wù kó rí.Gbọ́ ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n ènìyàn.

Òwe 22

Òwe 22:6-17