Òwe 21:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Ojú tí ó gbéga àti ọkàn ìgbéraga,ìmọ́lẹ̀ àwọn ènìyàn búburú, ẹ̀ṣẹ̀ ni!

5. Ètè àwọn olóye já sí èrèbí ìkánjú ṣe máa ń fa òsì kíákíá.

6. Ìṣúra tí a kójọ nípaṣẹ̀ ahọ́n tí ń parọ́jẹ́ ìrì lásán àti ìkẹkùn ikú.

7. Ìwà ipá àwọn ènìyàn búburú yóò wọ́ wọn lọ,nítorí wọ́n kọ̀ láti ṣe ohun tí ó tọ́.

Òwe 21