Òwe 21:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń fi ìlara ṣojúkòkòrò ní gbogbo ọjọ́:ṣùgbọ́n olódodo a máa fi fún ni kì í sì í dáwọ́ dúró.

Òwe 21

Òwe 21:18-31