Òwe 20:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Góòlù wà, iyùn sì wà rẹpẹtẹṣùgbọ́n, ahọ́n tí ń sọ ìmọ̀ gan an ni ọ̀ṣọ́ iyebíye.

Òwe 20

Òwe 20:11-21