Òwe 19:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aláìgbọ́n ọmọ jẹ́ ìparun baba rẹ̀,Aya tí ó máa ń jà sì dàbí ọ̀sọ̀ọ̀rọ̀ òjò.

Òwe 19

Òwe 19:8-15