Òwe 16:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY) Ti ènìyàn ni ìgbèrò inú ọkànṢùgbọ́n láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìdáhùn