Òwe 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òpè ènìyàn gba ohun gbogbo gbọ́ṣùgbọ́n Olóye ènìyàn ronú lórí àwọn ìgbéṣẹ̀ rẹ̀.

Òwe 14

Òwe 14:9-16