Òwe 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo olóye ènìyàn máa ń hùwà pẹ̀lú ìmọ̀Ṣùgbọ́n aláìgbọ́n a fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.

Òwe 13

Òwe 13:7-18