Òwe 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbéraga máa ń dá ìjà sílẹ̀ niṣùgbọ́n ọgbọ́n wà nínú àwọn tí ń gba ìmọ̀ràn.

Òwe 13

Òwe 13:1-14