Òwe 11:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa kórìíra òṣùwọ̀n èkéṣùgbọ́n òṣùwọ̀n òtítọ́ jẹ́ inú dídùn un rẹ̀.

2. Nígbà tí ìgbéraga bá dé, nígbà náà ni ìdójútì déṣùgbọ́n, pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀ ni ọgbọ́n ń wá.

Òwe 11