Orin Sólómónì 4:15-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
15. Ìwọ ni ọgbà oríṣun, kànga omi ìyè,ìṣàn omi láti Lẹ́bánónì wá.
16. Jí ìwọ afẹ́fẹ́ àríwákí o sì wá, afẹ́fẹ́ gúṣù!Fẹ́ lórí ọgbà mi,kí àwọn òórùn dídùn inú rẹ lè rùn jáde.Jẹ́ kí olùfẹ́ mi wá sínú ọgbà a rẹ̀kí ó sì jẹ àṣàyàn èso rẹ̀.