Oníwàásù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, ṣeé pẹ̀lú gbogbo agbára rẹ, nítorí kò sí iṣẹ́ ṣíṣe tàbí ìpinnu tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n nínú iṣà-òkú níbi tí ò ń lọ.

Oníwàásù 9

Oníwàásù 9:1-13