Oníwàásù 8:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun mìíràn tún wà tí kò ní ìtumọ̀, tí ó ń ṣẹlẹ̀ láyé olódodo tí ó ń gba ohun tí ó tọ́ sí òsìkà àti òsìkà tí ó ń gba ohun tí ó tọ́ sí olódodo. Mo ṣọ wí pé eléyìí gan-an kò ní ìtumọ̀.

Oníwàásù 8

Oníwàásù 8:11-17