Oníwàásù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ayé àìní ìtumọ̀ yìí ni mo ti rí gbogbo èyí:Ènìyàn olóòtìítọ́, ọkùnrin olódodo ń parun nínú òtítọ́ rẹ̀ìkà ènìyàn sì ń gbé ìgbé ayé pípẹ́ nínú ìkà rẹ̀.

Oníwàásù 7

Oníwàásù 7:7-17